ST Communications2024-03-252024-03-252023-10-02https://africarxiv.pubpub.org/pub/cwbpq2yyhttps://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1406https://doi.org/10.60763/africarxiv/1347https://doi.org/10.60763/africarxiv/1347https://doi.org/10.60763/africarxiv/1347Yoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/xq6jhA ṣàfikún ọjọ́-orí 15 sí 24 nínú ìwádìí àpawọ́pọ̀ṣe lórí HIV àti jẹjẹrẹ ní orílẹ̀-èdè South Africa, ẹ̀gbé tó tóbi tí ó jẹ́ àyọrísí ìsopọ̀ láàrin òsùwon àyẹ̀wò ajẹmọ́-HIV láti ilé-iṣẹ́ ibùdó àyẹ̀wò ètò-ìlera àpapọ̀ orílẹ̀-èdè àti ibùdó àpapọ̀ àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ jẹjẹrẹ. A ṣàkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn jẹjẹrẹ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ. A wo ìkanra láàrin àwọn jẹjẹrẹ náà àti ẹ̀yà-ìbí, ọdún ìbí, àti iye kuulu-ẹ̀jẹ̀ CD4 pẹ̀lú ìṣàmúlò módẹ́ẹ̀lì Cox àti òṣùwòn alátúntò ásáàdì (aHR).otherHIVA ṣàfikún ọjọ́-oríàyọrísí ìsopọ̀Àwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀-èdè South Africa tí ó ní HIV àti CD4 tó kéré súmọ́ ewu àtiní jẹjẹrẹ gidi gan-an.