ST CommunicationsPhilipp, L .Marion, J.Du Plessis, A.Tshibalanganda, M.Terblanche, J.2024-03-252024-03-252023-10-07https://africarxiv.pubpub.org/pub/erior7sehttps://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1351https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302Yoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/2urxfSíṣe òdiwọ̀n ìhun kòmóòkun àwọn kòkòrò àti àwọn ìyàtọ̀ wọn jẹ́ ìpèníjà torí kíkéré tí wọ́n kéré tí a ò lè fojú lásán rí. Níbí a gbé ìwọ̀n lórí ìwọ̀n kòmóòkun kòkòrò nipa lilo X-ray micro-tomography (µCT) wíwo (ni 15 µm ipinnu) lori alààyè, idin ti cerambycid Beetle Cacosceles newmannii tí wọ́n fún ní abẹ́rẹ́ ìfọ̀kàbalẹ̀ pẹ̀lú ara. Nínú ìwé yìí a pèsè ìwọ̀n dátà ní kíkún àti àwọn àwòṣe 3D fun ayẹ̀wò 12, tó pèsè dátà lórí àtúnlò àwọn ìtúpalẹ̀ àwòrán àti àwọn ìyàtọ̀ ìhun kòmóòkun tí a gbé kalẹ̀ nípasẹ̀ ọ̀nà pípín oríṣiríṣi àwòrán. Ìwọ̀n dátà tí a pèsè síbí pẹ̀lú àgbègbè kòmóòkun tí a pín gẹ́gẹ́ bí àwòṣe 3D.otherÒdiwọ̀nKòmóòkunÌpèníjàA lè lo ìlànà X-ray tí a ò lè fojú lásán rí láti fi máàpù àwọn ẹ̀ya ara kòkòrò kékeré