Ki wọ́n jẹ́ kí obìnrin kópa lásìkò tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́ àti tí wọ́n bá ń dán àwọn àgbàdo tí ó lè fara da ọ̀gbẹlẹ̀ wò

dc.contributor.authorST Communications
dc.date.accessioned2024-03-25T14:13:57Z
dc.date.available2024-03-25T14:13:57Z
dc.date.issued2023-10-02
dc.descriptionYoruba translation of DOI: 10.1007/978-3-319-76222-7_5
dc.description.abstractIpa tí ó lápẹẹrẹ ni àwọn obìnrin ń kó nínú pípèsè ohun-ọ̀gbìn àti ìdáàbòò oúnjẹ jíjẹ nínú ilé. Àmọ́ ṣá, ìkópa àwọn obìnrin nínú ìsedánwò àwọn ẹ̀rọ tí wọ́n pèsè fún ohun-ọ̀gbìn nínú-oko kéré. Nínú ìwádìí yìí, a lo àtòjọ-ìbéèrè tó ní ètò láti gba dátà, wọ́n fún àwọn àgbẹ̀ obìnrin 80 nínú ìṣedánwò àgbàdo tí ó lè fara da ọ̀gbẹlẹ (DT)̀ ní ilẹ̀ Pápá Southern Guinea (SGS) Ajẹmọ́-ohun-ọ̀gbìn ojú ọjọ́ Ẹkùn ti Nigeria. Ìwádìí náà fi hàn pé gbogbbo àwọn àgbẹ̀ obìnrin náà ni wọ́n ti lọ́kọ, bíi 23% wọn ni wọn kò lọ ilé-ìwé rárá, tí ìgbèdéke ọjọ́-orí wọn sì tó ẹni ọdún 43. Ní gbogbo àwọn ìbùdó ni àwọn àgbẹ̀ obìnrin ti gbé ẹ̀yà àgbàdo DT sí ipò tí ó dára jùlọ. Fún ìdí èyí a gbà á níyànjú pé kí àwọn àgbẹ̀ obìnrin máa kópa nínu ṣíṣe ìgbéǹde àti ìdánwo ráńpẹ́ fún àwọn òye tuntun lẹ́nu iṣẹ́ ohun ọ̀gbìn láti rí dájú pé ààbò wà fún oúnjẹ kí wọn ó sì ní ìdàgbàsókè ọlọ́jọ́ pípẹ́ nípasẹ̀ ìpèsè ìrànwọ́ fún iṣẹ́ ohun ọ̀gbìn.
dc.identifier.urihttps://africarxiv.pubpub.org/pub/6ve6ehes
dc.identifier.urihttps://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1419
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1360
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1360
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1360
dc.language.isoother
dc.subjectObinrin
dc.subjectIsedanwo
dc.subjectOhun-ogbin
dc.titleKi wọ́n jẹ́ kí obìnrin kópa lásìkò tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́ àti tí wọ́n bá ń dán àwọn àgbàdo tí ó lè fara da ọ̀gbẹlẹ̀ wò

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
71ba5474-f291-4419-830f-af5118fde07d.pdf
Size:
76.86 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.72 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: