A lè lo ìlànà X-ray tí a ò lè fojú lásán rí láti fi máàpù àwọn ẹ̀ya ara kòkòrò kékeré
dc.contributor.author | ST Communications | |
dc.contributor.author | Philipp, L . | |
dc.contributor.author | Marion, J. | |
dc.contributor.author | Du Plessis, A. | |
dc.contributor.author | Tshibalanganda, M. | |
dc.contributor.author | Terblanche, J. | |
dc.date.accessioned | 2024-03-25T07:35:44Z | |
dc.date.available | 2024-03-25T07:35:44Z | |
dc.date.issued | 2023-10-07 | |
dc.description | Yoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/2urxf | |
dc.description.abstract | Síṣe òdiwọ̀n ìhun kòmóòkun àwọn kòkòrò àti àwọn ìyàtọ̀ wọn jẹ́ ìpèníjà torí kíkéré tí wọ́n kéré tí a ò lè fojú lásán rí. Níbí a gbé ìwọ̀n lórí ìwọ̀n kòmóòkun kòkòrò nipa lilo X-ray micro-tomography (µCT) wíwo (ni 15 µm ipinnu) lori alààyè, idin ti cerambycid Beetle Cacosceles newmannii tí wọ́n fún ní abẹ́rẹ́ ìfọ̀kàbalẹ̀ pẹ̀lú ara. Nínú ìwé yìí a pèsè ìwọ̀n dátà ní kíkún àti àwọn àwòṣe 3D fun ayẹ̀wò 12, tó pèsè dátà lórí àtúnlò àwọn ìtúpalẹ̀ àwòrán àti àwọn ìyàtọ̀ ìhun kòmóòkun tí a gbé kalẹ̀ nípasẹ̀ ọ̀nà pípín oríṣiríṣi àwòrán. Ìwọ̀n dátà tí a pèsè síbí pẹ̀lú àgbègbè kòmóòkun tí a pín gẹ́gẹ́ bí àwòṣe 3D. | |
dc.identifier.uri | https://africarxiv.pubpub.org/pub/erior7se | |
dc.identifier.uri | https://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1351 | |
dc.identifier.uri | https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302 | |
dc.identifier.uri | https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302 | |
dc.identifier.uri | https://doi.org/10.60763/africarxiv/1302 | |
dc.language.iso | other | |
dc.subject | Òdiwọ̀n | |
dc.subject | Kòmóòkun | |
dc.subject | Ìpèníjà | |
dc.title | A lè lo ìlànà X-ray tí a ò lè fojú lásán rí láti fi máàpù àwọn ẹ̀ya ara kòkòrò kékeré |