Àwọn oníwádìí sọ pé fáírọ́ọ̀sì COVID-19 lè má tètè yírapadà, èyí tó jẹ́ kí ṣíṣe àjẹ́sára yá

Thumbnail Image

Date

2023-10-02

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Abstract

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ìgbà tó ti bẹ̀rẹ̀ ní ìparí osù Belu ọdún 2019 ní Wuhan, China. Lílo òye àti ṣiṣe àbójútó ìtànkálẹ̀ ìpilẹ̀-ara fáírọ́òsì náà, àwọn àbùdá agbègbè rẹ̀, àti ìdúróṣin rẹ̀ ṣe pàtàkì fún àti ṣe ìsàkóso ìtànkálẹ̀ àrùn náà àti fún ìdàgbàsókè àjẹsára káríayé tó bo gbogbo àwọn iṣan. Láti ìhà yìí, a ṣe àtúpalẹ̀ ìpìlẹ̀-ara 30,983 SARS-CoV-2 láti àwọn orílé-ède 79 tó wà ní oríṣiríṣi kọ́ńtínẹ́ẹ̀tì mẹ́fà tí a sì gbà láti 24 oṣù Ọpẹ́ ọdún 2019, títí dé 13 osù Èbìbí 2020, ní ìbámu pẹ̀lú àkójọ dátà ti GISAID. Àtúpalẹ̀ wa fi ààyè ìyàtọ̀ 3206 hàn, pẹ̀lú ìṣọ̀kan ìfọnká irúfẹ́ ìyípadà ní oríṣiríṣi agbègbè. Pẹ̀lú ìyàlẹ́nu, a ti ṣe àkíyèsí ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ìyípadà lóòrẹ̀kóòrè; ìyípadà 169 péré (5.27%) ní ìtànkálẹ̀ ìpìlẹ̀-ara tí ó tóbi jù pẹ̀lú 1%. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, àwọ́n àmúkù mẹ́rìnlá tí kò bára jọ (>10%) ní a ti ṣèdámọ̀ ní àwọn ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ibi ìpìlẹ̀-ara; mẹ́jọ nínú ORF1ab (nínú nsp2, nsp3, àyè awọ, RdRp, ẹ́líkeèsì, ẹksonukílìs àti ẹndoribonukílíìsì), mẹ́ta nínú amúaradàgbà nukilioscásíìdì, àti ọ̀kà nínú purotéènì mẹ́ta:

Description

Yoruba translation of DOI: 10.3390/pathogens9100829

Keywords

COVID-19, Àjàkálẹ̀, Ìpilẹ̀-ara

Citation