Àwọn aráàlú Uganda tó ní àrùn kọ̀kòrò HIV àti ẹ̀jẹ̀ ríru ò rí ìtọ́jú tí ó péye gbà

Thumbnail Image

Date

2023-10-02

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Abstract

Àwọn èèyàn tó ń gbé pẹ̀lú HIV (PLHIV) tó sì ń gba ìtọ́jú àìlera antiretroviral ní ewu púpọ̀ tó jẹ mọ́ àrùn ọkàn àti ti ẹ̀jẹ̀ (CVD). Asopọ̀ iṣẹ́ fún ẹ̀jẹ̀ ríru (HTN), èyí tó jẹ́ ewu CVD àkọ́kọ́, sínú àwọn ilé-ìwòsàn HIV tí wọ́n ṣe ìdúró fún ní orílé-èdè Uganda. Iṣẹ́ wa ìṣáájú ṣe àfihàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlààfo tí a lè lò fi sẹ àmúlò ìsopọ̀ ìtọ́jú HTN pẹ̀lu ọgbọ́ń ìtọ́jú HIV lẹ́sẹẹsẹ. Nínú iṣẹ́ ìwádìí yìí, a wá láti ṣàwárí àwọn ohun ìdènà sí ti àwọn tó wà ní ìdí ìbojúwo ìṣàkóso ìsopọ̀ HTN àti ìtọ́jú sí àwọn ilé ìwòsàn HIV ní Ilà-Oòrùn ilẹ̀ Uganda.

Description

Keywords

PLHIV, Antiretroviral, Àìlera

Citation