Àwọn aráàlú Uganda tó ní àrùn kọ̀kòrò HIV àti ẹ̀jẹ̀ ríru ò rí ìtọ́jú tí ó péye gbà

dc.contributor.authorST Communications
dc.date.accessioned2024-03-25T11:58:01Z
dc.date.available2024-03-25T11:58:01Z
dc.date.issued2023-10-02
dc.description.abstractÀwọn èèyàn tó ń gbé pẹ̀lú HIV (PLHIV) tó sì ń gba ìtọ́jú àìlera antiretroviral ní ewu púpọ̀ tó jẹ mọ́ àrùn ọkàn àti ti ẹ̀jẹ̀ (CVD). Asopọ̀ iṣẹ́ fún ẹ̀jẹ̀ ríru (HTN), èyí tó jẹ́ ewu CVD àkọ́kọ́, sínú àwọn ilé-ìwòsàn HIV tí wọ́n ṣe ìdúró fún ní orílé-èdè Uganda. Iṣẹ́ wa ìṣáájú ṣe àfihàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlààfo tí a lè lò fi sẹ àmúlò ìsopọ̀ ìtọ́jú HTN pẹ̀lu ọgbọ́ń ìtọ́jú HIV lẹ́sẹẹsẹ. Nínú iṣẹ́ ìwádìí yìí, a wá láti ṣàwárí àwọn ohun ìdènà sí ti àwọn tó wà ní ìdí ìbojúwo ìṣàkóso ìsopọ̀ HTN àti ìtọ́jú sí àwọn ilé ìwòsàn HIV ní Ilà-Oòrùn ilẹ̀ Uganda.
dc.identifier.urihttps://africarxiv.pubpub.org/pub/ty884ji0
dc.identifier.urihttps://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1372
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1323
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1323
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1323
dc.language.isoother
dc.subjectPLHIV
dc.subjectAntiretroviral
dc.subjectÀìlera
dc.titleÀwọn aráàlú Uganda tó ní àrùn kọ̀kòrò HIV àti ẹ̀jẹ̀ ríru ò rí ìtọ́jú tí ó péye gbà

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
452fc664-0fe4-4bfb-b378-f36395d274c3.pdf
Size:
86.47 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.72 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: