Àwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀-èdè South Africa tí ó ní HIV àti CD4 tó kéré súmọ́ ewu àtiní jẹjẹrẹ gidi gan-an.

Loading...
Thumbnail Image

Date

2023-10-02

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Abstract

A ṣàfikún ọjọ́-orí 15 sí 24 nínú ìwádìí àpawọ́pọ̀ṣe lórí HIV àti jẹjẹrẹ ní orílẹ̀-èdè South Africa, ẹ̀gbé tó tóbi tí ó jẹ́ àyọrísí ìsopọ̀ láàrin òsùwon àyẹ̀wò ajẹmọ́-HIV láti ilé-iṣẹ́ ibùdó àyẹ̀wò ètò-ìlera àpapọ̀ orílẹ̀-èdè àti ibùdó àpapọ̀ àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ jẹjẹrẹ. A ṣàkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn jẹjẹrẹ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ. A wo ìkanra láàrin àwọn jẹjẹrẹ náà àti ẹ̀yà-ìbí, ọdún ìbí, àti iye kuulu-ẹ̀jẹ̀ CD4 pẹ̀lú ìṣàmúlò módẹ́ẹ̀lì Cox àti òṣùwòn alátúntò ásáàdì (aHR).

Description

Yoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/xq6jh

Keywords

HIV, A ṣàfikún ọjọ́-orí, àyọrísí ìsopọ̀

Citation