UbuntuNet-Connect2024 Registration Now Open: https://ubuntunet.net/uc2024
 

Àwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀-èdè South Africa tí ó ní HIV àti CD4 tó kéré súmọ́ ewu àtiní jẹjẹrẹ gidi gan-an.

dc.contributor.authorST Communications
dc.date.accessioned2024-03-25T13:37:40Z
dc.date.available2024-03-25T13:37:40Z
dc.date.issued2023-10-02
dc.descriptionYoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/xq6jh
dc.description.abstractA ṣàfikún ọjọ́-orí 15 sí 24 nínú ìwádìí àpawọ́pọ̀ṣe lórí HIV àti jẹjẹrẹ ní orílẹ̀-èdè South Africa, ẹ̀gbé tó tóbi tí ó jẹ́ àyọrísí ìsopọ̀ láàrin òsùwon àyẹ̀wò ajẹmọ́-HIV láti ilé-iṣẹ́ ibùdó àyẹ̀wò ètò-ìlera àpapọ̀ orílẹ̀-èdè àti ibùdó àpapọ̀ àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ jẹjẹrẹ. A ṣàkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn jẹjẹrẹ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ. A wo ìkanra láàrin àwọn jẹjẹrẹ náà àti ẹ̀yà-ìbí, ọdún ìbí, àti iye kuulu-ẹ̀jẹ̀ CD4 pẹ̀lú ìṣàmúlò módẹ́ẹ̀lì Cox àti òṣùwòn alátúntò ásáàdì (aHR).
dc.identifier.urihttps://africarxiv.pubpub.org/pub/cwbpq2yy
dc.identifier.urihttps://africarxiv.ubuntunet.net/handle/1/1406
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1347
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1347
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.60763/africarxiv/1347
dc.language.isoother
dc.subjectHIV
dc.subjectA ṣàfikún ọjọ́-orí
dc.subjectàyọrísí ìsopọ̀
dc.titleÀwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀-èdè South Africa tí ó ní HIV àti CD4 tó kéré súmọ́ ewu àtiní jẹjẹrẹ gidi gan-an.

Files

Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
e9a9535e-34d5-46fb-9dd2-71110f923f1a.pdf
Size:
82.03 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.72 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: