A lè lo ìlànà X-ray tí a ò lè fojú lásán rí láti fi máàpù àwọn ẹ̀ya ara kòkòrò kékeré
Loading...
Date
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Abstract
Síṣe òdiwọ̀n ìhun kòmóòkun àwọn kòkòrò àti àwọn ìyàtọ̀ wọn jẹ́ ìpèníjà torí kíkéré tí wọ́n kéré tí a ò lè fojú lásán rí. Níbí a gbé ìwọ̀n lórí ìwọ̀n kòmóòkun kòkòrò nipa lilo X-ray micro-tomography (µCT) wíwo (ni 15 µm ipinnu) lori alààyè, idin ti cerambycid Beetle Cacosceles newmannii tí wọ́n fún ní abẹ́rẹ́ ìfọ̀kàbalẹ̀ pẹ̀lú ara. Nínú ìwé yìí a pèsè ìwọ̀n dátà ní kíkún àti àwọn àwòṣe 3D fun ayẹ̀wò 12, tó pèsè dátà lórí àtúnlò àwọn ìtúpalẹ̀ àwòrán àti àwọn ìyàtọ̀ ìhun kòmóòkun tí a gbé kalẹ̀ nípasẹ̀ ọ̀nà pípín oríṣiríṣi àwòrán. Ìwọ̀n dátà tí a pèsè síbí pẹ̀lú àgbègbè kòmóòkun tí a pín gẹ́gẹ́ bí àwòṣe 3D.
Description
Yoruba translation of DOI: 10.31730/osf.io/2urxf